Jump to content

Yoruba/Food and Fruits

From Wikibooks, open books for an open world
English Name Yoruba Name Notes
Orange Ọsàn òrom̀bó Fruit
Paw-paw Ìbẹ́pẹ Fruit
Banana Ọ̀gẹ̀dẹ̀ Fruit
Lime Ọsàn wẹ́wẹ́ Fruit
Corn Àgbàdo Fruit
Cherry Àgbálùmọ́ Fruit
Beans Ẹ̀wà Food
Rice Ìrẹsì Food
Bread Búrẹ́dì Food
Pottage Àsáró Food
Beans Cake Àkàrà Food
Garden Egg Ikàn Fruit
Cassava Ẹ̀gẹ́ Food
Bean pudding Mọ́í-mọ́í Food
Plaintain Ọ̀gẹ̀dẹ̀ Fruit
Pap Ògì Food
Yam Iṣu Food
Pounded yam Iyán Food
Sugarcane Rèké Fruit
Coconut Àgbọn Fruit
Pineapple Ọ̀pẹ òyìnbó Fruit
Mango Máńgòrò Fruit
Potato Ànàmọ́/Kúkúǹdùnkún Food
Cocoyam/Taro Iṣu Kóókò Food